Sola Allyson – ÌPÍN


Download ÌPÍN by SOLA ALLYSON MP3 – Lyrics & New Music Release

SOLA ALLYSON’s latest release, “ÌPÍN,” is a soulful and spiritually enriching track that has quickly captured the hearts of many. This new song beautifully blends heartfelt lyrics with captivating melodies, making it a must-have for any worship playlist.

Download ÌPÍN MP3 to immerse yourself in its profound message and exquisite composition. Whether you’re looking for music to enhance your prayer time or simply want to enjoy uplifting worship tunes, “ÌPÍN” offers a perfect combination of inspiration and artistry.

Be sure to check out the lyrics for “ÌPÍN” to fully appreciate the depth of SOLA ALLYSON’s message and connect more deeply with the song’s spiritual themes.

[DOWNLOAD MP3]

SOLA ALLYSON – ÌPÍN Lyrics

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN O

BEFORE I WAS FORMED IN MY MOTHER’S WOMB

BẸ́Ẹ̀NI

 

BEFORE I WAS FORMED IN MY MOTHER’S WOMB

MO TI YÀN’YÍ O

ÌPÍN MI RÈÉ O MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ ÒUN NÌKAN NI

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN ELÉDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SEE ALSO:  Joe L Barnes - Count Me In

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN ELÉDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN ELÉDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÈMI Ò TÌẸ̀ MỌ̀ MO KÀN Ń R’ÌRÌN MI LỌ NI

ÈMI Ò MỌ̀

 

MI Ò MỌ̀ B’Ó ṢE JẸ́

OJÚ U MI L’Ó LÀ TÍ MO FI MỌ̀

ÌPÍN NÁÀ RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

BEFORE I WAS FORMED NÍNÚ ÌYÁ À MI

L’A TI YÀN MÍ O

ÈMI NÁÀ RÈÉ O

ÒGO NI MÀÁ ṢE FÚN ỌBA T’Ó NI ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN MI

MI Ò MỌ̀ P’Ó MÁA LE B’Ó ṢE LE Ń’GBÀ YẸN

ṢÙGBỌ́N MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌDÀÀMÚ LÈ WÀ L’Ọ́NÀ ÌBÀNÚJẸ́ LÈ WÀ L’Ọ́NÀ

ṢÙGBỌ́N MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

L’ÈLÉTÒ ÌPÍN Ó TI DÁ MI PẸ̀LÚ ÌPÍN MI

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

ÀÁNÚ WÀ, ÌRÀNWỌ́ WÀ

ÀÁNÚ WÀ LÁTI ÒKÈ

LÁTI ÀGBÀLÁ ÌMỌ́LẸ̀

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ TÈMI

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

ÌMỌ́LẸ̀ TÈMI KÒ JỌ T’ẸLÒMÍÌ

Ọ̀DỌ̀ ONÍÌMỌ́LẸ̀ ṢÁÀ NÁÀ L’Ó TI WÁ

ÌMỌ́LẸ̀ TÈMI OLÚṢỌLÁ ÀṢÀKẸ́ ARẸ́SẸ̀TẸLẸ

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀. YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

SEE ALSO:  Phil Thompson x Victor Thompson - Jesus Lamb of God

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

KÍ ÀWỌN T’Ó BÍ MI

K’Ọ́N TÓ PÀDÉ ARA WỌN RÁRÁ

A TI YÀN MÍ O

PÉ ỌMỌ ÌMỌ́LẸ̀ L’ÈMI

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ N’ÌPÌLẸ̀ AYÉ

A TI YÀN’PÌN O

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

OHUN TÍ MO BÁ Ń’LẸ̀ Ó MÚ ÌDÀÀMÚ WÀ

ÌPÍN MI NI

SÍBÈ ÀÁNÚ WÀ

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN O

AYÉ Ń MO DÉ L’Ọ̀NÀ Á WỌ́

ÀÁNÚ WÀ SÍBẸ̀

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN O

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

MÀÁ FI Ṣ’Ẹ̀WÀ

MÀÁ FI Ṣ’ỌLÁ

S’Ọ́BA ÒKÈ T’Ó L’ỌLÁ

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

N’ÌPÌN TI DÚÓ

 

ỌJỌ́ Í B’Ẹ̀BẸ̀ ÀTI YỌ

ÌMỌ́LẸ̀ Í B’Ẹ̀BẸ̀ ÀTI TÀN

ÌṢẸ̀DÁ ÌMỌ́LẸ̀ L’ÈMI

MI Ò NÍ B’Ẹ̀BẸ̀ ÀTI HÀN

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

ỌJỌ́ Í B’Ẹ̀BẸ̀ ÀTI YỌ

ÌMỌ́LẸ̀ Í B’Ẹ̀BẸ̀ ÀTI TÀN

ÌṢẸ̀DÁ ÌMỌ́LẸ̀ L’ÈMI

MI Ò NÍ B’Ẹ̀BẸ̀ ÀTI HÀN

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

(ADMONITION)

 

YOU MUST WORK

YOU MUST WATCH

WATCH AND PRAY

WORK AND PRAY

Ọ̀RỌ̀ NI O

Ọ̀RỌ̀ ÌMỌ́LẸ̀ NI

YOU WILL WATCH AND PRAY

YOU WILL WORK AND PRAY

 

WÀÁ Ṣ’IṢẸ́ T’ Ó YẸ K’ÓO ṢE

WÀÁ RÌNNÀ T’Ó YẸ K’ÓO RÌN

PROCESS, STEP UPON STEP

L’A MÀÁ FI DÉ’BẸ̀ YẸN

BẸ́Ẹ̀NI, ỌMỌ MÁ GBÀGBÉ O

IṢẸ́ WÀ T’ÁA MÀÁ ṢE

IṢẸ́ WÀ T’ÁA MÀÁ ṢE

ṢÙGBỌ́N SÍBẸ̀ ÌMỌ́LẸ̀ YẸN

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

I HAVE MADE UP MIND

WHATEVER COMES ON MY WAY

MÀÁ TÀN’MỌ́LẸ̀ MÀÁ TÀN’MỌ́LẸ̀

AYÉ Á RÍ MI WỌ́N Á RÍ ÌMỌ́LẸ̀ OLÓGO

 

(ADMONITION)

 

SEE ALSO:  Sondae, Moflo - Courtyard

THAT THE OWNER OF TOMORROW

Ó NÍ ÌFẸ́ SÍ MI

ÌFẸ́ RERE L’Ó NI SÍ MI

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

(ADMONITION)

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

IT HAD BEEN PLANNED THAT I WILL BE LIKE THIS

ṢÙGBỌ́N MÀÁ RÌN MÀÁ RÌN L’Ọ́NÀ ÌMỌ́LẸ̀

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

Ó N’ÍBI TÍ ÌMÍSÍ TI Ń WÁ FÚN MI

ÌFẸ́ IBẸ̀ NI MÀÁ ṢE

ÌMÍSÍ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

O N’ÍBI TI ÌMÍSÍ TI MÀÁ NWA FÚN MI

ÌMÍSÍ YẸN MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

IBI ÌMỌ́LẸ̀ N’ÌMÍSÍ MI TI Ń WÁ

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

K’Ọ́LẸ̀ T’Ó SỌ

A TI YÀN’PÌN

ÌPÍN RÈÉ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O

ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O

MÀÁ FI Ṣ’ÒGO

 

ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀

ÌRAN YÍ LÁT’ORÍ I TÈMI YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN OGO

 

ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ, MI Ò R’ÍRÚ Ẹ̀ RÍ ṢÙGBÓN Á T’ORÍ MI BẸ̀RẸ̀ ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀

ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ N’ÍKỌ̀KỌ̀ NÍ GBANGBA O, ỌLỌ́RUN OGO

 

ÌRAN YÍ YÓÒ MÀÁ Ṣ’ ÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀

ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN ÒGO

 

ÌRAN MI YÓÒ MÁA Ṣ’ÀFẸ́RÍ Ẹ

KÒ ṢẸLẸ̀ RÍ NI MO GBỌ́

ṢÙGBỌ́N Á T’ORÍ Ì MI BẸ̀RẸ̀

IRAN MI YÓÒ MÀÁ WÀ NÍNÚ ÌFẸ́ RẸ

ỌLỌ́RUN ÒGO

 

ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀ T’Ó JÓÒKÓ S’ÓRÍ ÒBÍRÍ AYÉ

MÀÁ ṢÈ’FẸ́ Ẹ̀ RẸ

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Related Posts